
Watch the video for Ibile Mugabe by cdq exclusively on Eventriga TV
Cdq finally drops the video for Ibile Mugabe as directed by AdamsGud. The much anticipated music video was worth the wait.
WATCH DEEJAY AWESUM PERFORMANCE IN CALABAR WITH EVENTRIGA
Watch the video below and review the lyrical and visual contents
WATCH CDQ IBILE MUGABE BEHIND THE SCENE
Ibile Mugabe Lyrics
[Instrumental]
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
Woss!!!
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe emi ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
Woss!!!
[1]
I woke up dis morning, feeling like I need to do this
òpó l’omo araye tii tuu ni asiri bi ti noodles
Some niggas ain’t happy when you d one calling the shot
T’olohun ba fun won ni okun emi mi, they will cut it short
Many fake smiles ….afeni l’oju ma f’emi deenu
tori e ni mo se gbaradi incase t’oba le gbemu
No second chance for any nigga t’oba rokuu romii
SMS 4 Naira lo ma je ko mu kuronii
Won ni mo ti street* ju, kii s’ebi porsche, Moo je BB
Ibile Mugabe ……..(add to complete the lyrics)
E tara yin lopo fun oyinbo……………. (add to complete the lyrics)
K’elegbe mo egbe e lelegbe, Principal yato si V.C
Eegun t’oba ti naa ni tele k’ole gbowo mo
Butty turn street lo po nisin, k’osomo igboro mo.
Esee findings k’eto bèé si eni t’efe bèé si
(Chorus)
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe ibi-ibi-le Mugabe
Ibile Mugabe emi ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
ibi-ibi-le Mugabe
[2]
Omo to m’owo dele ni iya e n kii ni daansaki
Starboy mo n shana bi torchlight Zakky
Gbogbo ilekun ti won rope awon ti ni mo n ja key
Ohun ti agba fi n j’eko l’abe ewe, emi so mo hanky
Orin apala l’oro yin ko s’eni t’omajo
Awon ladder tiwon fun yin k’efi goke l’eti jo
Eti gbagbe pe alejo lowo, e n show pe e lejoo…
Lai mo pe ti ojo gidi ba ro, paanu si ma joo
Who would ever thought pe Omo Orile sii maa jooba si nu Lekki
…………………..(add to complete the lyrics) G-wagon pelu Bentley
Fi Gucci shaa marathon l’omo Oro Seyi Johnson
……..(add to complete the lyrics) Boss n leju every weekend, commit more sun.
Mi o ran anybody m’oran temi l’owo Obioma
Shout-out si Oba Goal, Iheanacho awon Onyeoma
Life is all about person wey sabi person person
Gba fun awon t’oju e lo ninu game ko ma lo s’esin